Ọ̀pákúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀pákúnlé

The home is full of the totem of the Òrìṣà oko.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀pá-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀pá - a totem pole of the deity of fertility
kún - fill
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kúnlé