Ọ̀ṣúnwùmíjù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnwùmíjù
The goddess Ọ̀ṣun is whom I love (the most).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-wù-mí-jù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautywù - be attracted to
mí - me
jù - the most
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
