Ọ̀ṣúnmúyìwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀ṣúnmúyìwá

1. Ọ̀ṣun brought this 2. Ọ̀ṣun brought honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀ṣun-mú...wá-èyí, ọ̀ṣun-mú...wá-iyì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beauty
mú...wá - bring
èyí - this (one)
iyì - value, worth, honour, goodwill


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Múyìwá

Múyì