Ọ̀ṣúnfowókẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnfowókẹ́
Ọ̀ṣun pampered (him/her) with money.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-fi-owó-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautyfi - used
owó - money, cowries
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL