Ọ̀ṣínbàjò
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣínbàjò
The king has returned from a journey.
Àwọn àlàyé mìíràn
"In his native Ijebu, one of the oldest and most distinct dialects of the Yoruba language, Ọsìn could also refer to a “child” and Ọsínbàjò (Osìn bọ̀ láti àjò) could then be interpreted to mean a child has returned from a journey." From https://www.thecable.ng/osibajo-osinbanjo-osinbajo-meet-nigerias-newest-politician-buharis-running-mate Ọṣìn (also sometimes written as Ọsìn or Ọshìn) is common in many Ìjẹ̀bú names like Ọsìnọ́wọ̀ or Ọ̀shítẹ̀lú, etc, referring to the Ọṣìn divinity.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọṣìn-bọ̀-àjọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọṣìn - king (as used in Ẹrú Ọṣìn: the King's slave)bọ̀ - return, come back
àjò - journey
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Yẹmí Ọ̀sínbàjò
the vice-president of Nigeria (2015- )