Ọ̀ṣúnyọmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúnyọmí
Ọ̀ṣun saved me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-yọ-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautyyọ - to remove, save
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Rachel Ọ̀ṣúnyọmí Fágúnwà
mother of renowned Yoruba author Daniel Fágúnwà