Ọ̀ṣápùàbí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣápùàbí
Ọ̀rìṣà did not destroy the gathering/celebration. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣà-ò-pa-ùà-bí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣà - Òrìṣà, the supreme sky deity Ọbàtáláò - did not
pa - kill, drown, quench
ùà - the society, a gathering, celebration; royal courtyard
bí - give birth to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI