Ẹrùogun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹrùogun

1. Spoils of war (Ẹrùogun) 2. The slave of Ògún (Ẹrúògún)



Àwọn àlàyé mìíràn

Depending on the tone marking, the name can mean many things.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹrù-ogun, ẹrú-ògún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹrù - load
ogun - warfare
-
ẹrú - slave
ògún -


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO