Ẹríayọ̀olúwabùkúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹríayọ̀olúwabùkúnmi

God's testimony of joy blessed me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀rí-ayọ̀-olúwa-bù-kún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀rí - testimony
ayọ̀ - joy
olúwa - lord, God
bùkún - add onto, bless
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL