Ẹnúyàmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹnúyàmí
An idiomatic expression meaning "I am surprised."
Àwọn àlàyé mìíràn
Given to a child born after something happens that was very surprising (often in a negative way)
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹnu-yà-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹnu - mouthyà - be open wide
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN