Ẹniafẹ́lamọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹniafẹ́lamọ̀
We only know whom we love.
Àwọn àlàyé mìíràn
This name derives from a common saying "Ẹni a fẹ́ la mọ, a kò m'ẹni tó fẹ́ ni." Meaning: We only know those whom we love. It's hard to know who exactly loves us back.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹni-a-fẹ́-ni-a-mọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹni - persona - we
fẹ́ - love, want
ni - is (whom)
a - we
mọ̀ - know
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL