Ẹniọlọ́runyàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹniọlọ́runyàn

The one chosen by God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹni-ọlọ́run-yàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹni - someone, person
ọlọ́run - God
yàn - select, choose


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL