Ẹlẹ́wìodò

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹlẹ́wìodò

The chief guardian of the river wealth



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹl-ẹ́wì-odò



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹl' - oní (the owner of)
ẹwì - cowrie shells
odò - river