Ẹlẹ́bùrúìkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹlẹ́bùrúìkẹ́

One with a suddenness of care.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is one of the cognomens used to praise God as the person capable of pleasantly surprising mankind.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-ẹbùrú-ìkẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - the owner of
ẹbùrú - surprise, suddenness
ìkẹ́ - care