Ẹgbẹ́yínká

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́yínká

Teams/My mates surround me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-yí...ká-n



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - equal mates, team, company
yí...ká - surround
n - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Ẹgbẹ́yímiká