Ẹgbẹ́jẹ́nráyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́jẹ́nráyọ̀
The Ẹgbẹ́ spirit allowed me find joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-jẹ́-n-rí-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritjẹ́ - permit, to exist, to be effective
n - me (mi)
rí - to see, to find
ayọ̀ - joy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA