Ẹgbẹ́gbémisókè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́gbémisókè
The Ẹgbẹ́ spirit raised me up.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-gbé-mi-sókè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritgbé - to carry, to lift
mi - me
sókè - up
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA