Ẹgbẹ́gbémisókè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́gbémisókè

The Ẹgbẹ́ spirit raised me up.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-gbé-mi-sókè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spirit
gbé - to carry, to lift
mi - me
sókè - up


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Gbémisókè