Ẹgbẹ́fúnmitọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́fúnmitọ́

The Ẹgbẹ́ spirit gave me (this child) to raise.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-fún-mi-tọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spirit
fún - to give to
mi - me
tọ́ - be proper, be on the right path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Ẹgbẹ́fúntọ́

Fúnmitọ́

Fúntọ́