Ẹgbẹ́dùnmóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́dùnmóyè
Ẹgbẹ́ is sweet with honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-dùn-mọ́-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritdùn - sweet, enjoyable
mọ́ - with
oyè - honor, chieftaincy ttle
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA