Ẹgbẹ́bámidélé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́bámidélé

Company accompanies me home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

Ẹgbẹ́-ba-mi-dé-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ẹgbẹ́ - company, society; Ẹgbẹ́ spirit.
bá - helped me
dé - arrive
ilé - home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA