Ẹgbẹ́bámiráyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́bámiráyọ̀
Ẹgbẹ́ spirit helps me find/see joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-bá-mi-rí-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritbá - helped me
mi - me
rí - to see, to find
ayọ̀ - joy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA