Ẹgbẹ́làńkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́làńkẹ́
Ẹgbẹ́ is what we are taking care of.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-ni-à-ń-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritni - is
à - we/one who
ń - continue to
kẹ́ - to pamper, care for
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA