Ẹgbẹ́fikẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́fikẹ́mi

The Ẹgbẹ́ spirit used this (child) to care for me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-fi-kẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spirit
fi - put
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Fikẹ́mi