Ẹgbẹ́fúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́fúnmi

The spirit gave her to me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-fún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - company, crew, team, club/agemates/spiritual society
fún - give
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fúnmi

Gbẹ́fúnmi