Ẹfúnyẹlé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúnyẹlé
Purity is befitting of the house.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-yẹ-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtáláyẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL