Ẹfúnlànà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúnlànà
Purity opened the path.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Adélànà, Ògúnlànà
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-là-ọ̀nà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtálálà - open, survive
ọ̀nà - road, lane, way, path
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL