Ẹfúnbọ́ládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹfúnbọ́ládé

The child of an O̩bàtálá adherent came with wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹfun-bá-ọlá-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹfun - purity (representing Ọbàtálá religion)
bá - together with
ọlá - wealth, success
dé - arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL