Ẹfúnyẹlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúnyẹlá
Purity (of Ọbàtálá) befits honor.
Àwọn àlàyé mìíràn
Ẹfun, ritual chalk, in certain contexts is associated with many deities including Ọbàtálá, Ọ̀ṣun, and Òrìṣàoko
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-yẹ-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtáláyẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
ọlá - honour, wealth, success, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
SAGAMU
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Mary Ẹfúnyẹlá Awólọ́wọ̀
mother of Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀