Ẹfúndoyin
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúndoyin
Purity has become sweet.
Àwọn àlàyé mìíràn
Names with Ẹfun as root are usually connected to Ọ̀ṣun or Ọbàtálá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-di-oyin
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whitenessdi - become
oyin - honey, sweetness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL