Ẹfúndẹ̀rọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹfúndẹ̀rọ̀

Purity (of Ọbàtálá) has become (or created) softness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹfun-di-ẹ̀rọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtálá
di - become
ẹ̀rọ̀ - ease, softness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Dẹ̀rọ̀