Ẹfúndùnní
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúndùnní
Ẹfun is sweet to have.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-dùn-ní
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtáládùn - sweet, enjoyable
ní - have
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN