Ẹfúndùnkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹfúndùnkẹ́

(The child of) purity is sweet to care for.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹfun-dùn-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtálá
dùn - to be sweet
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL