Ẹ̀ríolúwatósìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹ̀ríolúwatósìn

God's testimony is worthy to be praised



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀rí-olúwa-tó-sìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀rí - proof, testimony
olúwa - lord, God
tó - suffice for
sìn - worship


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Ẹ̀rí

Ẹ̀ríolúwa

Tósìn