Ẹ̀ríọ̀tun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹ̀ríọ̀tun

A new testimony.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀rí-ọ̀tun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀rí - witness, evidence
ọ̀tun - renewed, new


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN