Ẹ̀mílọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹ̀mílọlá

The breath of life is honorable.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀mí-ni-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀mí - life, breath, spirit
ni - is
ọlá - honour, wealth, success, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
AKURE



Irúurú

Ẹ̀míniọlá