Ṣóyọmbọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣóyọmbọ̀
1. The sorcerer saved and brought me (back). 2. The god Oko saved and brought me (back). [Verification needed].
Àwọn àlàyé mìíràn
Ṣó (short for Oṣó) usually refers to sorcerer but depending on the family it may also be short for Òrìṣàoko, also known as Oko, who is the god of farming and agriculture.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
Oṣó-yọ-mi-bọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Oṣó - sorcerer, Oko (the god of farming)yọ - to save, to rescue
mi - me
bọ̀ - to return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Fisáyọ̀ Ṣóyọḿbọ̀
Nigerian journalist.