Ṣótáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣótáyọ̀
The sorcerer is enough for joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-tó-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Òrìṣa oko (fertility deity)tó - suffice for
ayọ̀ - joy, mirth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN