Ṣópẹ̀yìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣópẹ̀yìn
The sorcerer called to those behind.
Àwọn àlàyé mìíràn
Oṣó is sometimes regarded as being short for the god of farming, Orìṣàoko
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-pe-ẹ̀yìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, the god of farming (Òrìṣà oko)pe - call
ẹ̀yìn - back, behind, future
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL