Ṣókẹ́nù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣókẹ́nù
The child cared for by the fertility divinity (Òrìṣà Oko) is/was lost.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is an àbíkú name given to a child born after a particular loss.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-kẹ́-nù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà oko)kẹ́ - pet, care for, take care of, cherish
nù - to lose
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA