Ṣófọlábọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣófọlábọ̀
The sorcerer has returned with wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(o)ṣó-fi-ọlá-bọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Oṣó divinity of fertility and farming, òriṣa okofi - use
ọlá - wealth
bọ̀ - return, arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN