Ṣóṣínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣóṣínà

The sorcerer opened the way.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(o)ṣó-ṣí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, Oṣó divinity of fertility and farming, òriṣa oko
ṣí - open
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Oṣọ́ṣínà