Ṣíjúwọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣíjúwọlá
(I) opened my eyes to wealth.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Ṣíjúwadé.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣí-ojú-wo-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣí - openojú - eyes
wò - look, stare at
ọlá - wealth, nobility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE