Ṣemóore

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣemóore

Made with goodness.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Ṣemílóore.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣe-mọ́-oore



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣe - make, do, create
mọ́ - with
oore - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL