Ṣemílóre
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣemílóre
Be kind to me.
Àwọn àlàyé mìíràn
A variant of Olúwaṣemílóre.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣe-mí-ní-ore
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣe - to do, to makemí - me
ní - in
ore - kindness, favour
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL