Ṣọlágbadé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣọlágbadé
Make nobility to receive royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣe-ọlá-gba-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣe - makeọlá - wealth, nobility
gba - receive
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL