Ṣọlákúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣọlákúnmi

Honor is made and added to me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣe-ọlá-kún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣe - make, create
ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige
kún - add to
mi - mine, me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Shọlákúnmi

Ṣọlákúmi

Fọlákúnmi

Olúṣọlákúnmi

Ọmọ́ṣọlákúnmi