Ṣẹ̀nbánjọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣẹ̀nbánjọ
Ùṣẹ̀n is in cooperation/agreement with me.
Àwọn àlàyé mìíràn
Ùṣẹ̀n is the family totem in honour of an Ijẹ̀bú-Igbó heir apparent, who was sacrificed to avert conquest of the town by enemies. Source: Odùbáyọ̀ Odùṣínà.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(ù)ṣẹ̀n-bá-n-jọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
(ù)ṣẹ̀n - Ùṣẹ̀n deitybá - together with
n - me
jọ - cooperate, agree
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Láolú Ṣẹ̀nbánjọ
artist.