Ṣópolú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣópolú
The sorcerer/fertility god has called the prominent one.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-pe-olú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, Òrìṣa oko (fertility deity)pe - call
olú - prominent one
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
David Ṣópolú Awólọ́wọ̀
father of Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀