Ṣóníyan

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣóníyan

The sorcerer has a joyful strut.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣó-ní-yan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà Oko)
- have
yan - to strut


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Shóníyan

Oṣóníyan